Gbagede Yoruba
 

 
EsinIslam Media: Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga

Wa Lori Koko Yi:   
[ Lọ si Ojule Aiyelujara Gbagede | Yan Koko Tuntun ]

Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga

Eyi Ni Bi Enu Se Ko Ba Bobrisky, Okunrin To N Se Bii Obirin: Won Ni Awon Olopa D
(Itan ni kikun... | 5890 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)

Eyi Ni Bi Enu Se Ko Ba Bobrisky, Okunrin To N Se Bii Obirin: Won Ni Awon Olopa Da Ayey Ojoobi E Ru - Bee Loun Naa Ti Salo

Lana-an gan-an ni omokuinrin kan ti oruko e n je Idris Okuneye, eni tawon eeyan tun mo si Bobrsiky pe eni odun mejidinlogon, sugbon dipo ayajo ayeye ohun, nise lawon olopaa kolu ileetura to fe lo, ti oro si di bo o lo o yago.

Oga gba nileese ijoba to n ri si Asa ati isese, Otunba Olusegun Runsewe ni okunrin to n se bii obinrin yii, Bobrisky yaju si, ki oloju si too se e, nise ni nnkan daru mo on lowo, toro si di bi bami-in mo on lowo bayii.

Ohun ta a gbo ni pe, lana-an gan-an ni Bobrisky loun yoo pate ariya nla, nibi to ti fe ko awon tie jo lati sayeye ojoobi, sugbon bo ti se n pete ariya yii lowo, bee lawon olopaa n so, bo si ti se ku dede ki won bere inawo ohun lawon agbofinro yade, bi won se le awon alabase e danu niyen o, ti won ni Bobrisky paapaa na papa bora, tawon eeyan ko si mo ibi to gba lo.


(Itan ni kikun... | 5890 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)
 


Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga

O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
(Itan ni kikun... | 2259 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)

O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku L'ekoo

Bi e ti n ka iroyin yi, ko tii daju pe ewon ko ni Baba agbaaya eni ogota odun kan, Clement Ikechukwu Ogenyi yoo ti lo eyi to ku ninu igbesi aye re, peluu bi ashiri e she tu pe o fipa ja ibale omodun meerin kan ta a foruko bo lashiri.

Agbegbe Otukpo nipinle Benue nishele naa ti waye lopin ose to koja yi, to si je pe die loku kawon eeyan dana sun un nita gbanga.

A gbo pe oogun oyinbo kan ti won pe ni Vitamin C ni Iya omo naa ran an pe ko lo o ra wa, ko too di pe baba agba radarada naa fogbon tan an wole, to si fipa ja ibale e.

Ki i she pe ashiri dee de tu sita, bi ko she bi won she lomo naa rin de ile pada lo mu ifura dani fun iya re, to si ye abe omo re wo. Ariwo 'E gba mi o' ni won lobinrin naa mu bo enu, ko too di pe won loo ka Ikechukwu mole.


(Itan ni kikun... | 2259 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)
 


Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga

Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
(Itan ni kikun... | 2237 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)

Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata Lo So Bee

Ilu mon on ka oshere tiata orileede Ghana nni, Xandy Kamel ti so pe latigba toun ti wa kekere loun ti n gbadun ibalopo, paapaa nigba toun wa ni ipele kerin nile eko alakobere, iyen Primary 4 loun ti n ni ibalopo, ti ko si jo oun loju mo rara.

Kamel lo soro yi nigba to n tako iroyin kan to n lo kaakiri ori ayelujara pe ibalopo lo fi n gba okiki nidi ishe tiata, ati pe bi ko ba gbe idi sile fawon alakoso ere, won kii lo lati kopa.

O ni iroyin ti won n gbe kaakiri naa ki i she toun nitori pe kaakiri ilu ti won ti bi oun loun gbajumo sii, ko da, nigba toun wa nile eko girama


(Itan ni kikun... | 2237 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)
 


Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga

Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
(Itan ni kikun... | 2432 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)

Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji

Gbogbo ilu Makurdi, nipinle Benue lo fee le daru laaro oni nigba ti won ba oku omoge arewa kan ta a ko tii mo oruko re dasiko ti a shakojopo iroyin yi tan ninu igbo kan to wa niwaju shooshi ti won pe ni Grace Tower.

Ohun ta a gbo ni pe awon gendekunrin kan ni won fipa wo odomobinrin naa, ti won si ko ibasun fun leyo-kookan, titi to fi jade laye.

Iwe Irohin Yoruba gbo pe she ni won ja omobinrin naa sihoho omolaubi, ti won si fi asho dii lenu pa, ki won too bere sii fi kinni abe won dana si omoge arewa naa labe.

Igba ti won ni agbara omobinrin yi ko fee gbe mo, leyin to ti bebe titi, sugbon ti won ko da a lohun, la gbo pe o gba ekuru je lowo ebora.


(Itan ni kikun... | 2432 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)
 


Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga

Owo Te Wahab Nibi To n Ti n Se'Kinni' Fomo Odun Mewaa Legbee Ogiri
(Itan ni kikun... | 1427 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)

Lati Owo Johnson Akinpelu, Abeokuta

Owo Te Wahab Nibi To n Ti n Se'Kinni' Fomo Odun Mewaa Legbee Ogiri

Bi won ba n wa oniranu aye atorun, omokunrin eni ogun odun kan ti won n pe ni Wahab Abdul Azeez lo ye ki won mu pelu iwa idoti to hu, to tun fi ra awon ebi e lara.

Lose to koja lowo te Wahab ni koro ile kan ti won ko ti i ko pari, nibi to ti n ba omobinrin eni odun mewaa kan lo po. Adugbo kan ti won n pe ni 'Sparkling Estate', ni Isheri Olofin, nisele naa ti waye.Gege bi Omooba Muyiwa Adejobi to je agbenuso fawon olopaa nipinle Ogun se wi, iya omo naa ran an nise ni ti Wahab fi tan an wo koro ile akopati naa, to si bere si i ba a sun lori iduro.


(Itan ni kikun... | 1427 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)
 


Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga

Mumini Lu Magun Lara Iyawo Oloye Ilu n'Iyana-Offa
(Itan ni kikun... | 2322 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)

Lati Owo Akoroyin Olootu

Mumini Lu Magun Lara Iyawo Oloye Ilu n'Iyana-Offa

Iku okunrin awako ero kan to n je Mumini niluu Lalupon, nipinle Oyo, ti ko itiju nla ba awon ebi ati ojulumo re bayii pelu bi okiki ti se kan kiri pe aisan ibalopo kan ti won n pe ni magun ni baba naa lu.

Lara iyawo baba oloye kan niluu Iyana-Offa ni won ni Mumini ti lu magun, sugbon ko si eni ti i ba mo pe magun lokunrin awako yii lu bi ko ba se pe oun funra re fi enu ara e so o nitori ojo keje to kan ijangbon ohun ni kinni naa ja si iku fun un.

Awon olugbe ilu Iyana-Offa fidi e mule pe o pe ti Mumini, eni tawon eeyan tun mo si Gidado pelu iyawo baba oloye naa to n je Iya Ade ti jo n se wolewode ikoko. Bo si tile je pe oko-iyawo ko mo si ibasepo yii, sibe, ara fu baba naa nitori irin tiyawo e maa n rin lopo igba ki i ye e, bee lobinrin naa ki i gba ko ba a lajosepo ninu ile.


(Itan ni kikun... | 2322 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)
 


Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga

Imeh Ha Sowo Olopaa L'Ekoo, Aburo Iyawo e Lo Se Kinni un Fun
(Itan ni kikun... | 2896 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)

Lati Owo Oluyinka Soyemi

Imeh Ha Sowo Olopaa L'Ekoo, Aburo Iyawo e Lo Se Kinni un Fun

Iwadiigidi lo n lo lowo bayii lori iwa ainitiju ti afurasi odaran eni odun merindinlogoji kan, Imeh Akpan, hu latari bo se ba aburo iyawo re lasepo ni tipa. Ose to koja ni ileese olopaa ipinle Eko safihan okunrin naa lolu-ileese won to wa n'Ikeja, nibi to ti n seju pakopako nigba to n so ohun to ri lobe to fi waro owo.

Iwadii Iwe Iroyin Yoruba fi han pe agbegbe Obalende ni afurasi ohun n gbe pelu iyawo re, omo to fipa ba lo po ta a foruko bo lasiiri yii si wa lodo won. Agbo pe lati kekere lomo naa ti n gbe pelu molebi naa, aburo iyawo ni, sugbon o jinna si egbon re gan-an lojo ori.


(Itan ni kikun... | 2896 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)
 


Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga

Aliyu Fipa Ba Omo Odun Metala Lo Po n'Ilorin, Lo Ba Doyun
(Itan ni kikun... | 1851 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)

Lati Owo Akoroyin Olootu

Aliyu Fipa Ba Omo Odun Metala Lo Po n'Ilorin, Lo Ba Doyun

Kayeefi si ni isele to sele laduugbo Sakpefu, ni ona Lade, niluu Ilorin, si n je fawon eeyan nigba tokunrin olokada kan, Aliyu Tsado, to je omo ogun odun ki ero to gbe mole, to si fipa ba a lo po, eyi to pada waa ja soyun fomo naa.

Omodebinrin omo odun metala naa ti a foruko bo lasiiri ni akoroyin wa gbo pe adugbo kan naa loun ati Aliyu n gbe, asiko ti okunrin olokada naa pade re loju ona lo pe e pe dipo ti yoo maa fese rin, koun fokada gbe e dele. Leyin ti Aliyu gbe omo ohun lori okada re, ile ara re lo morile, nibi to ti fipa ba omo naa lasepo.

Iwadii awon olopaa fi han pe gbogbo bomo yii se pariwo pe kawon eeyan gba oun kale lowo okunrin naa ni ko reni kankan dide si i nitori paro ni gbogbo adugbo ohun da. Leyin ojo die la gbo pe baba omo naa sakiyesi pe o n re omo oun, idi ree to fi mu un lo sosibitu 'Cottage' to wa laduugbo Lade, niluu Ilorin, nibe ni won ti fidi e mule pe omodebinrin yii ti loyun.


(Itan ni kikun... | 1851 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)
 


Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga

Adebowale Atawon Egbe e Fipa Ba Omo Odun Metala Lo Po
(Itan ni kikun... | 1683 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)

Lati Owo Akoroyin Olootu

Adebowale Atawon Egbe e Fipa Ba Omo Odun Metala Lo Po

Afi ki ijoba ipinle Eko tete wa nnkan se soro ifipa-ba-ni-lo-po to n fi gbogbo igba waye ko too di pe o buru ju bo se wa yii lo loro to n tenu awon ero iworan kootu majisreeti Yaba jade lose to koja nigba ti won gbo esun ifipa-ba-ni-lo-po ti won fi kan awon omodekunrin meta kan ti ojo-ori won ko ju odun merinla si merindinlogun lo.

Ohun ti a gbo ni pe omobinrin omo odun metala kan ti a foruko bo lasiiri ni awon olujejo naa, iyen Elijah Adebowale, Suleiman Balogun ati Shefiu Adam pelu awon meta kan towo ko ti i te fipa ba lasepo lojo karun-un, osu kewaa, odun yii, nile akoku kan to wa laduugbo Olopade, ni Iju-Ishaga, l'Ekoo.


(Itan ni kikun... | 1683 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)
 


Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga

Ale Lo Maa N Fi Moto Gbe Iyawo Mi Wale Lati Ibi Ise Lalaale Jimoh
(Itan ni kikun... | 2707 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)

Lati Owo Olawale Ajao, Ibadan

Ale Lo Maa N Fi Moto Gbe Iyawo Mi Wale Lati Ibi Ise Lalaale — Jimoh

Bi ejo ti okunrin birikila kan, Jimoh Alli, ro ni kootu ba se e tele pelu bo se so pe ale lo maa n gbe iyawo oun wale lati ibi ise lalaale, afaimo ni ko ni i je pe ale ohun lobinrin naa yoo ba lo gbeyin, iyen bi ile-ejo ba tu igbeyawo won ka.

Iyawo birikila yii, Titilayo Alli, lo ro kootu ibile Ojaba to wa ni Mapo, n'Ibadan, lati tu igbeyawo olodun mewaa to wa laarin oun ati oko re ka lojo Eti, (Fraide), to koja. O ni okunrin naa ki i se ojuse oko le oun atawon omo re lori, eyi to mu koun ko jade nile e ninu osu kejila, odun to koja. Sugbon oun ti waa ri i bayii pe igbese naa ko fi bee lagbara to, afi ki ile-ejo kuku tu igbeyawo awon ka patapata.

Ninu awijare re, oko iyawo so pe awawi lasan ni iyawo oun n se nitori gbogbo ojuse oko loun n se lori iyawo atawon omo oun ninu ile, ati pe nitori o n yan ale, ti ife okunrin naa si ti ko si i lori lo se pe ejo naa.


(Itan ni kikun... | 2707 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)
 


Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga

'Omo Egbon Mi Loko Mi Fun Loyun, Mi O Fe e Mo'
(Itan ni kikun... | 1987 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)

Lati Owo Akoroyin Olootu

'Omo Egbon Mi Loko Mi Fun Loyun, Mi O Fe e Mo'

Adajo kootu ibile kan n'Ilesa ti tu igbeyawo ogbon odun to wa laarin Arabinrin Folake to je eni aadota odun atoko re, Kolade, toun je ogota odun ka lori esun tobinrin naa fi kan oko re pe o fun omo egbon oun kan to n je Kemi to n gbe lodo awon loyun.

Nigba to n soro niwaju adajo, Folake salaye pe oko oun je alagbere, sugbon o ti fiwa naa ba ara re je lodo awon ebi oun bayii pelu bo se fun Kemi to je omo odun metadinlogun loyun.

Oyun naa lo ni won gbiyanju lati se, sugbon to ko lati baje leyin tomo naa ti lo opolopo oogun ibile.


(Itan ni kikun... | 1987 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)
 


Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga

Abel Se 'Kinni' Fomo Odun Mesan-an L'Ondo, Ladajo Ba Ni Ko Loo Fe
(Itan ni kikun... | 1730 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)

Lati Owo Akoroyin Olootu

Abel Se 'Kinni' Fomo Odun Mesan-an L'Ondo, Ladajo Ba Ni Ko Loo Fewon Odun Marun-un Jura

O daju pe bi okunrin kan toruko re n je Onoja Abel ba n fowo lasan fa, yoo ti maa gbadun ara re ninu ogba ewon Olokuta to fikale siluu Akure, nibi tadajo ile-ejo majisreeti kan niluu naa pase pe ko ti loo maa se faaji fodun marun-un lori bo se jebi esun fifipa ba omodebinrin eni odun mesan-an kan lo po.

Isele naa waye losu to koja, ni nnkan bii aago mefa irole ninu ogba kan ti won ti n ta omi inu ora lagbegbe High School, l'Akure, nibi ti Abel ti fogbon tan omo naa toruko re n je Precious Nwakocha, to si fipa ba a lo po.


(Itan ni kikun... | 1730 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)
 


Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga

Okunrin Mi-in N Se Kinni un Fun Iyawo Mi Ninu Ile Wa, Mi O Fe e Mo Babatunde
(Itan ni kikun... | 1790 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)

Lati Owo Akoroyin Olootu

Okunrin Mi-in N Se Kinni un Fun Iyawo Mi Ninu Ile Wa, Mi O Fe e Mo — Babatunde

Kootu ibile kan n'Ilesa ni Ogbeni Babatunde, eni ogoji odun, gbe iyawo re, Omolola, lo lori esun agbere to fi kan an, o si ro ile-ejo naa pe ko tu won ka lai fakoko sofo.

Nigba ti Babatunde n soro niwaju adajo lo salaye pe ni nnkan bii ose meji seyin loun ba iyawo oun, Omolola, pelu okunrin kan to n je Adetayo lori beedi oun ti won n ba ara won sere ife.

Babatunde ni ise olokada loun n se, sugbon lasiko tomo awon, Tope, jade nileewe loun gbe e lo sile, nibi toun ti ba iyawo oun ti won n ko ibasun fun un lowo. O ni nitori toun ko fe ki Adetayo ohun salabaapade iku ojiji latowo oun ni oun fi loo fejo re sun lagoo olopaa to wa n'Ijamo, niluu Ilesa.


(Itan ni kikun... | 1790 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)
 


Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga

Animasahun Niyawo Ti Mo Fe, Mi O Se Mo Ayokunle
(Itan ni kikun... | 2710 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)

Lati Owo Oluseye Iyiade, Akure

Animasahun Niyawo Ti Mo Fe, Mi O Se Mo — Ayokunle

Afi k'Olorun yaa tete da si wahala to ti ridii jokoo ninu idile kan l'Akure, bi bee ko, igbeyawo odun mejidinlogun ohun ti wa ni bebe ati fori sanpon pelu bi baale ile naa se wo iyawo re wa si kootu koko-koko to wa niluu naa pe ki adajo fopin si ibasepo olodun gbooro to wa laarin oun pelu iyawo re kia.

Okunrin eni ogoji odun naa, Bamidele Ayokunle lo wo iyawo e, Folasade Ayokunle, wa si kootu to n gbejo loko-laya to wa l'Oke-Eda, niluu Akure, to si fesun agbere kan an. O ni iyaale ile naa ko mo enu i yipada bi okunrin ba kenu si i, bee ni ko si mo on ko fun gbogbo okunrin to ba ti gbe e sunmo on.


(Itan ni kikun... | 2710 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)
 


Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga

Larry Fipa Ba Omo Odun Mejo Lo Po N'Iju, Ni Won Ba Wo o Dele-ejo
(Itan ni kikun... | 1414 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)

Lati Owo Olowoake Latifat

Larry Fipa Ba Omo Odun Mejo Lo Po N'Iju, Ni Won Ba Wo o Dele-ejo

Okunrin eni odun metadinlogbon kan, Larry Atipko, ni won safihan re bii afurasi odaran nile-ejo majisreeti to fikale si Yaba lose to koja lori esun pe o fipa ba omodebinrin odun mejo kan to je omo araale re lo po pelu ipa.

Gege bi ohun ta a ri gbo, ki i se igba akoko ree tokunrin ti won pe loree timotimo ebi omode yii yoo fipa mu omo naa mole ninu yara re ba a ni nnkan po. Sugbon eyi to se keyin lojo ketadinlogun, osu kesan-an, odun yii, lowo ti te olujejo naa to n gbe lojule Kin-in-ni, laduugbo Tunji Adesayo, Fagba, Iju.

Agbenuso ijoba, Rita Momah, so pe anfaani pe ile kan naa ni okunrin yii pelu awon obi omo naa n gbe lo lo lati wo omo ohun wonu yara e, to si se bee ba iyen lo po lai tie wo pe o kere pupo soun.


(Itan ni kikun... | 1414 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)
 


Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga

Awon Omo Keekeeke Loko Mi n Gbe Kiri, Mi O Se Mo Folake
(Itan ni kikun... | 1629 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)

Lati Owo Akoroyin Olootu

Awon Omo Keekeeke Loko Mi n Gbe Kiri, Mi O Se Mo — Folake

Arabinrin Folake, eni ogota odun ti gbe oko re, Ogbeni Odewole, lo sile-ejo ibile kan n'Ilesa lori esun agbere sise pelu bo se maa n ba awon odomobinrin tojo ori won ko ju ogun odun lo sagbere, ti yoo si maa kowo fun won.

Gege bi Folake to je osise-feyinti ileese ologun se so, o ni lati igba ewe Odewole, lo ti n se agbere, sugbon kaka kewe agbon re de, lile lo n le si i nitori bi ko se fiwa naa sile titi di asiko yii to ti darugbo.

Foluke tesiwaju pe oun ti lojo lori lati gbe iru igbese toun gbe yii, ifokanbale ati alaafia loun nilo titi ti olojo yoo fi de.


(Itan ni kikun... | 1629 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)
 


Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga

Ishola Fipa Ba Omo Odun Mesan-an Lo Po N'Ilorin, O Tun Fi Ankasiifu Nu Oju
(Itan ni kikun... | 1788 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)

Lati Owo Olawale Ajao, Ibadan

Ishola Fipa Ba Omo Odun Mesan-an Lo Po N'Ilorin, O Tun Fi Ankasiifu Nu Oju Ara Re

Owo ajo Sifu Difensi ipinle Kwara ti te arakunrin eni odun metadinlogbon kan, Oyetunde Anjola Ishola, latari pe o huwa to se ni ni kayeefi pelu bo se fipa ba omodebinrin omo odun mesan-an kan ti a foruko bo lasiiri lo po, to si tun fi ankasiifu nu oju ara re.

Gege bi alukoro ajo naa nipinle Kwara, Henry Bilesanmi, se salaye fun akoroyin wa, ojo kejo, osu kesan-an, odun yii, ni Ishola huwa naa ni nnkan bii aago mejo koja iseju marundinlogun. Baba omo yii, Hakeem Mustapha, lo mu esun to ajo naa wa pe Ishola ti fipa ba omo oun obinrin ti ko ju omo odun mesan-an lo lo po.(Itan ni kikun... | 1788 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)
 


Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga

Owo Ajo Sifu Difensi Te Wolii To Fipa Ba Omo Odun Meeedogun Lo Po L'Ondo
(Itan ni kikun... | 6059 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)

Lati Owo Olawale Ajao, Ibadan

Owo Ajo Sifu Difensi Te Wolii To Fipa Ba Omo Odun Meeedogun Lo Po L'Ondo

Lojo Abameta, Satide, ose to koja lohun-un, lowo ajo Sifu Difensi ipinle Ondo te okunrin wolii kan nibi to ti n sere egele pelu omodebinrin kan, Tosin, okan ninu awon omo ijo re to je eni odun meeedogun.

Gege bi ohun t'Iwe Irohin Yoruba fidi e mule nipa isele naa, wolii ohun ti won pe oruko re ni Jacob Olasupo Ojomo to je oludasile ijo Kerubu ati Serafu, to wa ni Apata Iloro, lagbegbe Oke-Ijebu, niluu Akure, ni won fesun kan pe bo se n ba omodebinrin naa lo po, bee lo n gba nnkan mo nnkan fun iya omo yii.(Itan ni kikun... | 6059 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)
 


Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga

Olode Ile-eko Alakoobere Fipa Ba Omoleewe Lo Po N'Ilorin
(Itan ni kikun... | 2275 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)

Lati Owo Olayinka Adedayo

Olode Ile-eko Alakoobere Fipa Ba Omoleewe Lo Po N'Ilorin

Ogbeni olode kan, Appolos Isaiah, ti fipa ba odomodebinrin omo odun mesan-an kan lo po ni ile eko to ti n sise ode laduugbo Taiwo-Isale, niluu Ilorin, bayii.

Gege bi akoroyin wa se gbo, ojo kejidinlogun, osu to koja, nisele naa waye. Isaiah ni iwadii akoroyin wa fihan pe o n sise pelu ileese eleto aabo Ogboye-s Security Company ti won si fi i si ile eko alakoobere Methodist Nursery and Primary School' to wa ni adugbo TaiwoIsale.

Akoroyin wa ri i gbo pe nise ni Isaiah fogbon pe omodebinrin naa ti a foruko bo lasiiri yii, to si tan an wo ile ode to wa ninu ogba ileewe naa, nibe lo si ti fipa ba a lo po.(Itan ni kikun... | 2275 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)
 


Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga

Aye Yii Ti Baje O! Omo Odun Meta Ni Hassan Fipa Ba Lo Po N'Ilorin
(Itan ni kikun... | 1651 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)

Lati Owo Taofeek Surdiq

Aye Yii Ti Baje O! Omo Odun Meta Ni Hassan Fipa Ba Lo Po N'Ilorin

Ileese olopaa ipinle Kwara ti taari okunrin olokada kan, Hassan Bawa, eni odun mejidinlogoji lo si kootu majisreeti to wa niluu Ilorin niwaju Adajo A.M Ibrahim latari pe o fipa ba omo odun meta kan lo po.

Gege bi esun ti agbefoba to n rojo tako o nile-ejo fi kan Hassan, ni nnkan bii aago mejila osan ojo kokandinlogun, osu kesan-an, odun yii, ni Arabinrin Abibat Ojo to n gbe ni abule Aboto Oja, nijoba ibile Asa, nipinle Kwara, mu esun lo si tesan olopaa ni Afon pe lojo kejidinlogun, osu to koja yii ni oun de lati ibi ise ni nnkan bii aago meje ojo naa, toun si ri i pe oun ko ri omo oun obinrin omo odun meta ta a foruko bo lasiiri.(Itan ni kikun... | 1651 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)
 


Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga

Asiri pasito to n ba awon iyawo oniyawo sun n'Ibadan tu
(Itan ni kikun... | 7630 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)

Lati Owo Olawale Ajao, Ibadan

Iroyin Yoruba

Lakooko ti aawe lenti awon omoleyin Jesu n lo lowo, ti opopolo Kristeni n toro idariji ese, ti won si n tera mo ise rere lati ri ijoba Olorun wo, iyawo oniyawo lokunrin iranse Olorun kan, Pasito Sunday Moradeyo, n ba sun kiri, nise lo n loo ka won mo oode oko won, to si n ko ibasun fun won karakara.

Oke aimoye iyawo oniyawo ni Pasito Sunday ti ko ni aya loode yii ti se bee ba lasepo, oun paapaa so pe oun ko le ranti iye won lori, nitori o kere tan, oun ko le ma ba obinrin kan lo po lojumo, bee, odun karun-un ree toun ti bere ise buruku ohun.

Iwe Iroyin Yoruba gbo pe lati ojule de ojule, soobu kan si ekeji lokunrin to pera e leni ogbon odun yii n gbe kinni naa loo ka awon obinrin olobinrin mo. Ko si ohun meji to maa n ba won so koja oro nipa ise idande ati igbala atorunwa, ka si too wi, ka too fo, o ti da adura nla bole bii owara ojo.


(Itan ni kikun... | 7630 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)
 


Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga

Sunday ki iyawo ore re mole n'Ilorin, lo ba fipa ba a lo po
(Itan ni kikun... | 1306 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)

Lati Owo Stephen Ajagbe, Ilorin

Sunday ki iyawo ore re mole n'Ilorin, lo ba fipa ba a lo po

Odomokunrin eni odun metalelogun kan, Sunday Akano, ti wo gau bayii nitori esun ti won fi kan an pe o ki iyawo ore re mole, ile-ejo si ti pase ko si wa lahaamo ogba ewon.

Afurasi ohun lo fogbon tan omobinrin to je iyawo ore re yii wa sinu ile re, nibi to ti ki i mole ni tipa, to si se e basubasu. Agbegbe Adewole, niluu Ilorin, nisele ohun ti waye ko too di pe ileese olopaa 'D Division' to wa ni Adewole gbe ejo omokunrin ohun wa si eka to n sewadii iwa odaran ni olu ileese olopaa nipinle Kwara leyin towo te e.


(Itan ni kikun... | 1306 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)
 


Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga

Mudasiru pa iyawo re ti pelu oyun osu meji, lo ba sa lo siluu oyinbo
(Itan ni kikun... | 1642 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)

Lati Owo Akoroyin Olootu

Mudasiru pa iyawo re ti pelu oyun osu meji, lo ba sa lo siluu oyinbo

Iyaale ile eni odun metalelogbon kan, Alimat Alaya, to n gbe lagbegbe Airport, niluu Ilorin, ti kegbajare lo sile-ejo, nibi to ti ni ki won tu igbayawo olodun mejo oun pelu oko oun, Mudasiru Alaya, ka nitori okunrin naa ti pa oun ti lo siluu oyinbo.

Obinrin ohun to ni ise tisa loun yan laayo salaye fun ile-ejo koko-koko kan niluu Ilorin pe oun ko nifee okunrin naa mo. O ni latigba toun ti wa ninu oyun osu meji loko oun ti gba ilu London lo, latigba naa si ni ko ti weyin wo rara.

O ni, ''Lati bii odun mejo bayii lo ti wa niluu London, to si ko lati wa sile. Odun 2007 lo ti kuro lorile-ede Naijiria, inu oyun osu meji ni mo wa nigba naa, omo si ti pe odun meje bayii ti ko foju kan baba re.''


(Itan ni kikun... | 1642 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)
 


Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga

Asiri tu, ase nitori obinrin ni won se gun Sina pa n 'Ilesa
(Itan ni kikun... | 1747 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)

Lati Owo Akoroyin Olootu


Asiri tu, ase nitori obinrin ni won se gun Sina pa n 'Ilesa


Bi iro ba lo logun odun, ojo kan soso ni otito yoo ba a. Leyin odun merin tokunrin kan ti won n pe ni Lekan ti gun enikeji re toruko re n je Sina lobe pa nibi ayeye Ikije Oba ilu Ilahun, Oba Lawrence Olamiju Ajayi, lopin ose ko koja yii ni ooto to wa nidii oro naa foju han gbangba niluu Ilesa tisele naa ti waye.


Iwadii Iwe Iroyin Yoruba fidi e mule pe Oloogbe Sina je omo egbe okunkun ti won n pe ni ‘Eiye', ti Lekan naa si je omo egbe okunkun mi-in ti a ko mo oruko re lasiko ti a n ko iroyin yii jo.(Itan ni kikun... | 1747 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)
 


Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga

Garuba ba omo odun meji lo po ni Somolu, lo ba ni oun kan ba a foso lasan ni
(Itan ni kikun... | 2367 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)

Lati Owo Akoroyin Olootu


Garuba ba omo odun meji lo po ni Somolu, lo ba ni oun kan ba a foso lasan ni


Ileese olopaa ti wo okunrin olokada kan, Garuba Abdulraman, eni ogbon odun lo si kootu majisreeti to wa l'Ebute-Meta lori esun ti won fi kan an pe o fipa ba omodebinrin omo odun meji kan taa foruko bo lasiiri lo po ni tipatipa, bee lo tun gba anti omo naa lesee ninu.


Gege bi Iwe Iroyin Yoruba se gbo, isele naa waye ni nnkan bii aago mokanla aabo aaro ojo kokanlelogun, osu keji, odun yii, lagbegbe Somolu, niluu Eko, iyen nigba ti iya omo odun meji ohun loo ki aburo re, Alimat Muazu, ti won si sadeede wa omo ti. Ibi ti won ti n wa a lenikan ti ta won lolobo pe oun ri Garuba pelu omo kan lowo. Kia ni won ti to okunrin omo ipinle Niger naa lo sile akoku kan to n sun.(Itan ni kikun... | 2367 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)
 


Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga

Nitori ti ko gbe e jade lojo ayajo ololufe, iyawo dana sun oko e l'Ado-Ekit
(Itan ni kikun... | 3646 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)

Lati Owo Solomon Adewoye, Ado-Ekiti


Nitori ti ko gbe e jade lojo ayajo ololufe, iyawo dana sun oko e l'Ado-Ekiti


Opo eeyan loro naa si n ya lenu, bee ni awon kan ko tete gba eti won gbo nigba ti won gbo iroyin odidi iyawo ile to mo-on-mo dana sun oko e nitori pe iyen ko gbe e jade lojo ayajo ololufe to waye lose meji seyin.


Isele buruku naa waye laduugbo Idolofin, niluu Ado-Ekiti, lale ojo ayajo ololufe, iyen lojo kerinla, osu to koja yii. Arabinrin Bukola Ogidiolu to je eni ogbon odun ati oko re, Ogbeni Abimbola Ogidiolu ni isele naa sele si.


Gege bi awon toro naa soju e se so fun akoroyin wa, nise ni Bukola so fun oko e laaaro ojo naa pe ko gbe oun jade lale kawon loo se faaji, sugbon iyen pee de lati ibi ise, obinrin naa si so pe awon ale e to gbe jade lo je ko pe, ati pe oun yoo ko o logbon.(Itan ni kikun... | 3646 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)
 


Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga

N'Ilesa, Aluko le iyawo e jade nile lori esun agbere
(Itan ni kikun... | 1661 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)

Lati Owo Akoroyin OlootuN'Ilesa, Aluko le iyawo e jade nile lori esun agbereBi ile-ejo kaakiri orile-ede yii se n yanselodi bayii ni Ogbeni Aluko, eni ogota odun ti sedajo abele pelu bo se le iyawo re, Arabinrin Arike to je eni aadota odun jade nile lori esun agbere.

Eni toro naa soju e so pe l«Ojoru, Wesde, ose to koja yii ni Aluko ko ipa ati ikuuku bo Arike leyin to wole laago kan oru, ti ko si le salaye ohun to sele.

Nigba ti Iwe Iroyin Yoruba n ba Ogbeni Aluko soro nile re lopopona Omi-eran, nijoba ibile IlaOorun Ilesa, o ni aago mesan-an ale loun ti n pe Arike sori foonu, sugbon ko gbe e. Aago kan oru lo wole, ko si salaye nipa ode ariya to lo.


(Itan ni kikun... | 1661 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)
 


Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga

Odetola lu magun lara iyawo e n'Ilesa, eemeta lo gbokiti
(Itan ni kikun... | 1779 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)

Lati Owo Bisi Adesoye, Ilesa

Odetola lu magun lara iyawo e n'Ilesa, eemeta lo gbokiti

Ogbeni Odetola, eni ogorin odun to je oluko-feyinti ti kagbako iku ojiji pelu bo se lu magun lori iyawo re, Arabinrin Arike l'Ojoru, Tosde, ose to koja.

Oloogbe Odetola feyinti ninu ise oluko lodun to koja, bee l'Iwe Iroyin Yoruba gbo pe okunrin naa ni afojusun pe o maa ko lo sinu ile to n ko lodun to pari yii.

Odetola la gbo pe o bi omo merin, iyen Folake, Dupe, Alaba ati Oyekunle. Folake to je akobi wa nileewe fasiti kan ni orile-ede yii, awon to ku si wa ni ileewe girama ati ileewe alakoobere nipinle Osun.(Itan ni kikun... | 1779 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)
 


Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga

Aye yii ma ti waa baje o! Owo te Sunday ati Laudu nibi ti won ti n ba ara won su
(Itan ni kikun... | 1441 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)

Lati Owo Akoroyin Olootu

Aye yii ma ti waa baje o! Owo te Sunday ati Laudu nibi ti won ti n ba ara won sun n'Ibadan

Nitori pe won ka won mobi ti won ti n huwa to buru jai, to si le da omi alaafia ilu ru nipa biba ara won lo po, ileese olopaa ipinle Oyo ti taari awon okunrin meji kan, Sunday Gabriel, eni odun merindinlaaadota ati Audu, eni ogun odun sile-ejo majisreeti to n jokoo n'Iyaganku, niluu Ibadan, ni yara igbejo kerin, niwaju Adajo K.Y Durosaro Tijani lati so tenu won.(Itan ni kikun... | 1441 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)
 


Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga

N'Ibadan, Tisa Ba Awon Akekoo Re Meji Lo Po, Bee Tegbon-taburo Ni Won
(Itan ni kikun... | 1546 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)

Lati Owo Kayode Omotosho, Ibadan

N'Ibadan, Tisa Ba Awon Akekoo Re Meji Lo Po, Bee Tegbon-taburo Ni Won

Kayeefi nla si loro oluko ileewe alakoobere Calvary Heritage Primary School to wa ni Oluyole, n'Ibadan, Olayinka Oludare Folarin, si n je fun opo eeyan to wa nile-ejo Majisreeti yara igbejo Keji to wa ni Iyaganku, n'Ibadan, nigba ti won fesun kan an pe o fi tipa ba tegbon-taburo lasepo.

Gege bi olopaa to n soju ijoba ni kootu naa, Inspekito S.Ogunremi, se so, ni l'Ojobo, Tosde, ose to koja, o ni Olayinka Oludare Folarin, eni odun mejidinlogoji mu akekoo re omo odun mewaa ti a foruko bo lasiiri lo si koro kan nileewe yii lojo kokanlelogun, osu karun-un, odun yii, ni nnkan bii aago mokanla koja iseju marundinlogbon owuro, to si fi tipatipa ba a lajosepo.(Itan ni kikun... | 1546 Awọn baiti Die e sii | Fẹ lati ọrọIwoye? | Idinwo Rẹ Lori Itan: 0)
 


 

EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And IslamAfrica.Com