Gbagede Yoruba
 

 
N'Ibadan, Tisa Ba Awon Akekoo Re Meji Lo Po, Bee Tegbon-taburo Ni Won
 
Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga
Lati Owo Kayode Omotosho, Ibadan

N'Ibadan, Tisa Ba Awon Akekoo Re Meji Lo Po, Bee Tegbon-taburo Ni Won

Kayeefi nla si loro oluko ileewe alakoobere Calvary Heritage Primary School to wa ni Oluyole, n'Ibadan, Olayinka Oludare Folarin, si n je fun opo eeyan to wa nile-ejo Majisreeti yara igbejo Keji to wa ni Iyaganku, n'Ibadan, nigba ti won fesun kan an pe o fi tipa ba tegbon-taburo lasepo.

Gege bi olopaa to n soju ijoba ni kootu naa, Inspekito S.Ogunremi, se so, ni l'Ojobo, Tosde, ose to koja, o ni Olayinka Oludare Folarin, eni odun mejidinlogoji mu akekoo re omo odun mewaa ti a foruko bo lasiiri lo si koro kan nileewe yii lojo kokanlelogun, osu karun-un, odun yii, ni nnkan bii aago mokanla koja iseju marundinlogbon owuro, to si fi tipatipa ba a lajosepo.Esun eyi lo lo tako abala 218 iwe ofin to de iwa odaran tipinle Oyo todun 2000, ti ijiya nla si wa fun un labe ofin ohun.Ogunremi tesiwaju pe lojo kan naa, ni asiko kan naa, se lo tun ba egbon omodebinrin yii tiyen je omo odun mokanla lo po.
Gege bi Iwe Irohin Yoruba se gbo, se ni tisa yii maa n mu ipara (cream), ti yoo si fi pa ori nnkan omokunrin re ko too huwa ibi owo re. Nigba ti won n bi afurasi yii leere pe se o jebi tabi ko jebi awon esun ti won fi kan an, o ni oun ko jebi pelu alaye pe ise esu ni.Adajo ile-ejo ohun, Adajobinrin S.Oyediran pa a lase pe ki Folarin si maa loo gbategun logba ewon to wa l'Agodi, titi ti igbejo a tun fi waye lojo kejila, osu kefa, odun yii.


 Posted By Ifiranse Eleyi Je Wednesday, June 25 @ 23:26:06 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 

Comments 💬 التعليقات
 

For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا

Awọn ọna asopọ ti o jọmọ

· Die sii Nipa Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga
· Iroyin Nipasẹ MediaYorubaTeam


Ọpọlọpọ Itan Ka Nipa Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga:
O Sele! Iya Nimota Lo Oogun Ti Oyan E Fi Maa Tobi Si i, Loko Ba Da Eru E Sita: B


Iwọn Abala

Apapọ Dimegilio: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

Jọ̀wọ́ Gba Ẹ̀ẹ̀kejI ki o sI dIbo fun Abala YIi:

O tayọ
O dara pupọ
O dara
Deede
Buburu


Aṣayan


 Ọrẹ-itẹwe Ọrẹ-itẹweAkole Atoka Agbo-Oro

Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga

"N'Ibadan, Tisa Ba Awon Akekoo Re Meji Lo Po, Bee Tegbon-taburo Ni Won" | Buwolu wọle/Ṣẹda Eto Akọsilẹ | 0 Awon Alaiye


Awọn asọye jẹ Ohun ini nipasẹ Iwe ifiweranṣẹ. A Ko Lodidi Fun Akoonu wọn. Nibayi, A Pe Awọn oluka lati jabo Eyikeyi Abusive, Unsuitable And/tabi Islamophobic Content

Ko si awọn ọrọIwoye Ti o gba laaye Fun Aisinisi, Jọwọ Forukọsilẹ
 

EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And IslamAfrica.Com