Victoria Fi Obe Gun Oko Re Pa; Ladajo Ba Ni Ki Won Loo Yegi Fun Un
Victoria Fi Obe Gun Oko Re Pa; Ladajo Ba Ni Ki Won Loo Yegi Fun Un
Lagbala iroyin la ti gbo pe adajo ile ejo giga kan nipinle Bayelsa, Onidajo Nayai Aganaba ti pase pe ki won loo yegi fun obinrin eni ogbon odun kan, Victoria Gagariga lori esun pe o pa oko re, Henry Gagariga.
Adajo Nayai so pe gbogbo eri to wa niwaju oun lo fidii re mule pe olujejo lo gun oko re lobe pa latari owu-jije to fa wahala laarin won lojo kerin osu keji odun 2015.
O ni pelu eleri mefa ti won jeri tako obinrin naa nile ejo, iwadi ti fidii re mule pe obinrin yii nikan lo wa ninu ile pelu oko re lojo isele naa ati pe obe lo fi gun un lorun ti iyen si gbabe ku lojo naa.
Posted By
Ifiranse Eleyi Je Saturday, October 12 @ 14:05:40 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
"Victoria Fi Obe Gun Oko Re Pa; Ladajo Ba Ni Ki Won Loo Yegi Fun Un" | Buwolu wọle/Ṣẹda Eto Akọsilẹ | 0 Awon Alaiye
Awọn asọye jẹ Ohun ini nipasẹ Iwe ifiweranṣẹ. A Ko Lodidi Fun Akoonu wọn. Nibayi, A Pe Awọn oluka lati jabo Eyikeyi Abusive, Unsuitable And/tabi Islamophobic Content
Ko si awọn ọrọIwoye Ti o gba laaye Fun Aisinisi, Jọwọ Forukọsilẹ