Gbagede Yoruba
 

 
O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
 
Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku L'ekoo

Bi e ti n ka iroyin yi, ko tii daju pe ewon ko ni Baba agbaaya eni ogota odun kan, Clement Ikechukwu Ogenyi yoo ti lo eyi to ku ninu igbesi aye re, peluu bi ashiri e she tu pe o fipa ja ibale omodun meerin kan ta a foruko bo lashiri.

Agbegbe Otukpo nipinle Benue nishele naa ti waye lopin ose to koja yi, to si je pe die loku kawon eeyan dana sun un nita gbanga.

A gbo pe oogun oyinbo kan ti won pe ni Vitamin C ni Iya omo naa ran an pe ko lo o ra wa, ko too di pe baba agba radarada naa fogbon tan an wole, to si fipa ja ibale e.

Ki i she pe ashiri dee de tu sita, bi ko she bi won she lomo naa rin de ile pada lo mu ifura dani fun iya re, to si ye abe omo re wo. Ariwo 'E gba mi o' ni won lobinrin naa mu bo enu, ko too di pe won loo ka Ikechukwu mole.

Ogun idile to fee foun sheleya ita gbangba ni won lo n tenu mo pe o ti oun de odo omo naa, to si je pe nigba toun she e tan loju oun sheshe la

Awon araadugbo ni won so pe ki won lo o fa le awon olopaa lowo, ki won ma ba a jebi nipa shishe idajo lowo ara won.

BABA ARUGBO FIPA FA IDI OMODUN MERINLA YA NINU ILE AKOKU L'EKOO

Owo ileeshe olopaa ipinle Eko ti te baba agba radarada kan ti won loo fipa ba omodebinrin eni odun merinla kan sun ninu ile akoku kan l'Ekoo.

Bo tile je pe titi dasiko ti a ko iroyin yi tan ni Baba naa, ti won pe oruko re ni Aliyu Ali Mohammed shi n bebe pe ki won she oun jeje, tori pe ishe eshu ni, ati pe leyin toun she e tan loju oun sheshe la, sibe ohun tawon kan n so ni pe ki won je ki baba naa lo o lo eyitoku aye re logba ewon.

Peace Estate to wa niluu Ekoo la gbo pe Aliyu fipa wo omodebinrin naa ta a foruko bo lashiri wo, to si fipa bo pata e, ko too bere sii ko ibasun fun un karakara, ta a si tun gbo pe she lo fi asho di omo naa lenu lasiko naa.

Nigba to n fidi ishele naa mule fun wa, agbenuso fawon olopaa ipinle Ekoo, Bala Elkana so pe okan lara awon to mo nipa ishele naa, Harrison Chukwereuke lo foro naa to ileeshe won to wa ni Iba leti lojo keji oshu yi, tawon si rii pe loooto ni leyin opolopo iwadii.

O wa je ko di mimo pe Baba agbaaya naa ko ni pe e foju bale ejo.

 Posted By Ifiranse Eleyi Je Sunday, September 01 @ 03:05:54 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 

Comments 💬 التعليقات
 

For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا

Awọn ọna asopọ ti o jọmọ

· Die sii Nipa Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga
· Iroyin Nipasẹ MediaYorubaTeam


Ọpọlọpọ Itan Ka Nipa Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga:
O Sele! Iya Nimota Lo Oogun Ti Oyan E Fi Maa Tobi Si i, Loko Ba Da Eru E Sita: B


Iwọn Abala

Apapọ Dimegilio: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

Jọ̀wọ́ Gba Ẹ̀ẹ̀kejI ki o sI dIbo fun Abala YIi:

O tayọ
O dara pupọ
O dara
Deede
Buburu


Aṣayan


 Ọrẹ-itẹwe Ọrẹ-itẹweAkole Atoka Agbo-Oro

Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga

"O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku" | Buwolu wọle/Ṣẹda Eto Akọsilẹ | 0 Awon Alaiye


Awọn asọye jẹ Ohun ini nipasẹ Iwe ifiweranṣẹ. A Ko Lodidi Fun Akoonu wọn. Nibayi, A Pe Awọn oluka lati jabo Eyikeyi Abusive, Unsuitable And/tabi Islamophobic Content

Ko si awọn ọrọIwoye Ti o gba laaye Fun Aisinisi, Jọwọ Forukọsilẹ
 

EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And IslamAfrica.Com