Gbagede Yoruba
 

 
Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
 
Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata Lo So Bee

Ilu mon on ka oshere tiata orileede Ghana nni, Xandy Kamel ti so pe latigba toun ti wa kekere loun ti n gbadun ibalopo, paapaa nigba toun wa ni ipele kerin nile eko alakobere, iyen Primary 4 loun ti n ni ibalopo, ti ko si jo oun loju mo rara.

Kamel lo soro yi nigba to n tako iroyin kan to n lo kaakiri ori ayelujara pe ibalopo lo fi n gba okiki nidi ishe tiata, ati pe bi ko ba gbe idi sile fawon alakoso ere, won kii lo lati kopa.

O ni iroyin ti won n gbe kaakiri naa ki i she toun nitori pe kaakiri ilu ti won ti bi oun loun gbajumo sii, ko da, nigba toun wa nile eko girama

O wa a je ko di mimo pe kii she ibalopo loun fi n gba okiki, nitori pe kii she nnkan to jo oun loju mo lati fi di olokiki nidi ishe naa.


BI MO SHE N DALEMOSHU N KO ITIJU BA MI PUPO, MI O SI SHISHE ASHEWO O - ADAKU PARIWO SITA

Gbajumo soro ori redio nni, Omotunde Adebowale topo awon ololufe e tun mo si Loolo ti je ko di mimo pe kii she ebi oun pe oun n dalemoshu, toun si tun je iya n da gbe, sugbon ti ko si nnkan toun fe e she sii.

Loolo tawon to tun mo ninu gbajugbaja sinima olose-ose nni, iyen Jenifa tun mo si Adaku lo soro naa lasiko to n tu peere-peere oro fun ileeshe iroyin BBCYORUBA lonii nibi iforowero ti won she fun un.

Obinrin naa so pe ki i she gbogbo dalemoshu lo n she ashewo, bo tile je pe awon kan n she e, sugbon iyen ko so pe koun she e, tori ishe toun yan laayo ko faaye gba iru iwa bee.

Omo bibi ipinle Ogun naa tun soro lori ikora-eni-sile, to si so pe enu araye l'ebo ninu oro igbeyawo, nitori ohun ti won ma so ni pe ki lo de too she soro sita tabi o kuku ti n soro ju.

Oshere yii royin oun ti oju obinrin to ti ko oko sile n ri lawujo Yoruba.

Bee lo so pe boun she n dalemoshu ti n di nnkan itiju foun, nitori pe pupo ninu awon ore oun lawon oko won ti n le lodo oun, pe ki won yera foun tori pe oun ko si nile oko.

O ni ki i she nnkan to wu oun ni boun she n dalemoshu, ati pe ko si eni to wu lati dalemoshu nile aye yi.

Adaku ni awon eeyan maa n so pe awon omo obinrin ti ko si nile oko ko le yanju, sugbon Olorun ju eda lo.

 Posted By Ifiranse Eleyi Je Sunday, September 01 @ 03:00:07 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 

Comments 💬 التعليقات
 

For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا

Awọn ọna asopọ ti o jọmọ

· Die sii Nipa Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga
· Iroyin Nipasẹ MediaYorubaTeam


Ọpọlọpọ Itan Ka Nipa Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga:
O Sele! Iya Nimota Lo Oogun Ti Oyan E Fi Maa Tobi Si i, Loko Ba Da Eru E Sita: B


Iwọn Abala

Apapọ Dimegilio: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

Jọ̀wọ́ Gba Ẹ̀ẹ̀kejI ki o sI dIbo fun Abala YIi:

O tayọ
O dara pupọ
O dara
Deede
Buburu


Aṣayan


 Ọrẹ-itẹwe Ọrẹ-itẹweAkole Atoka Agbo-Oro

Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga

"Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata" | Buwolu wọle/Ṣẹda Eto Akọsilẹ | 0 Awon Alaiye


Awọn asọye jẹ Ohun ini nipasẹ Iwe ifiweranṣẹ. A Ko Lodidi Fun Akoonu wọn. Nibayi, A Pe Awọn oluka lati jabo Eyikeyi Abusive, Unsuitable And/tabi Islamophobic Content

Ko si awọn ọrọIwoye Ti o gba laaye Fun Aisinisi, Jọwọ Forukọsilẹ
 

EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And IslamAfrica.Com