Gbagede Yoruba
 

 
Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
 
Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji

Gbogbo ilu Makurdi, nipinle Benue lo fee le daru laaro oni nigba ti won ba oku omoge arewa kan ta a ko tii mo oruko re dasiko ti a shakojopo iroyin yi tan ninu igbo kan to wa niwaju shooshi ti won pe ni Grace Tower.

Ohun ta a gbo ni pe awon gendekunrin kan ni won fipa wo odomobinrin naa, ti won si ko ibasun fun leyo-kookan, titi to fi jade laye.

Iwe Irohin Yoruba gbo pe she ni won ja omobinrin naa sihoho omolaubi, ti won si fi asho dii lenu pa, ki won too bere sii fi kinni abe won dana si omoge arewa naa labe.

Igba ti won ni agbara omobinrin yi ko fee gbe mo, leyin to ti bebe titi, sugbon ti won ko da a lohun, la gbo pe o gba ekuru je lowo ebora.

Bo tile je pe gbogbo akitiyan lati ba agbenuso fawon olopaa ipinle naa soro titi dasiko ta a shakojopo iroyin yi tan lo ja si pabo, sugbon ti a gbo pe ishe iwadii shi n lo lowo.

AREWA OMOGE JI TELIFIShAN NLA NI OTEELI

Bi ki i ba a she opelope awon eleyinju aanu kan ni, boya won ki ba ti dana sun odomobinrin arewa kan, ti won pe oruko re ni Laurenta, eni ti won loo wo oteeli lo, to si lo o ji okan lara awon amohunmaworan, iyen telifishan ti won lo n lo nibe.

Oteeli kan ti won pe ni Kevleyn, eyi to wa nipinle Delta la gbo pe Laurenta loo ji gbe, ati pe oun peluu orekunrin re kan, tiyen ti na papa bora ni won jo gbimo papo ji telifishan naa gbe.

Iwe Irohin Yoruba gbo pe ose kan gbako ni Laurenta ati orekunrin re fi n gbe ni oteeli naa, latari owo ti won san sibe, ti won si n gbadun ara won daadaa.

Won ni inu baagi nla kan ti won n pe ni ''Ghana Must Go'' ni Laurenta gbe telifishan naa pamo si, asiko to si n gbe e jade ni lawon esho daa duro lati beere nnkan to wa ninu baagi naa, to si lawon eru tawon gbe debe ni.

Bi won she gba baagi naa lowo e ni tipatipa lo ba bere sii bebe pe ki won she oun jeje. Awon eleyinju aanu la gbo pe won gba won nimonran lati fa Laurenta le awon olopaa lowo.

A ti e gbo pe orekunrin Laurenta naa ti ji asho inura, agboorun (umbrella) ati kokoro to je ti oteeli naa salo peluu etanje wi pe oun fee lo ran nnkan nita. Leyin wakati keta la gbo pe Laurenta naa gbe telifishan, sugbon ti ashiri re pada tu sita.

Bee lawon kan ti e tun so pe Laurenta ti ji milionu kan naira din legberun lona igba (800,000) naira lowo okunrin kan ti won jo sun laipe yi.

 Posted By Ifiranse Eleyi Je Sunday, September 01 @ 02:54:49 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 

Comments 💬 التعليقات
 

For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا

Awọn ọna asopọ ti o jọmọ

· Die sii Nipa Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga
· Iroyin Nipasẹ MediaYorubaTeam


Ọpọlọpọ Itan Ka Nipa Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga:
O Sele! Iya Nimota Lo Oogun Ti Oyan E Fi Maa Tobi Si i, Loko Ba Da Eru E Sita: B


Iwọn Abala

Apapọ Dimegilio: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

Jọ̀wọ́ Gba Ẹ̀ẹ̀kejI ki o sI dIbo fun Abala YIi:

O tayọ
O dara pupọ
O dara
Deede
Buburu


Aṣayan


 Ọrẹ-itẹwe Ọrẹ-itẹweAkole Atoka Agbo-Oro

Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga

"Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji" | Buwolu wọle/Ṣẹda Eto Akọsilẹ | 0 Awon Alaiye


Awọn asọye jẹ Ohun ini nipasẹ Iwe ifiweranṣẹ. A Ko Lodidi Fun Akoonu wọn. Nibayi, A Pe Awọn oluka lati jabo Eyikeyi Abusive, Unsuitable And/tabi Islamophobic Content

Ko si awọn ọrọIwoye Ti o gba laaye Fun Aisinisi, Jọwọ Forukọsilẹ
 

EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And IslamAfrica.Com