Gbagede Yoruba
 

 
Ishola Fipa Ba Omo Odun Mesan-an Lo Po N'Ilorin, O Tun Fi Ankasiifu Nu Oju
 
Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga
Lati Owo Olawale Ajao, Ibadan

Ishola Fipa Ba Omo Odun Mesan-an Lo Po N'Ilorin, O Tun Fi Ankasiifu Nu Oju Ara Re

Owo ajo Sifu Difensi ipinle Kwara ti te arakunrin eni odun metadinlogbon kan, Oyetunde Anjola Ishola, latari pe o huwa to se ni ni kayeefi pelu bo se fipa ba omodebinrin omo odun mesan-an kan ti a foruko bo lasiiri lo po, to si tun fi ankasiifu nu oju ara re.

Gege bi alukoro ajo naa nipinle Kwara, Henry Bilesanmi, se salaye fun akoroyin wa, ojo kejo, osu kesan-an, odun yii, ni Ishola huwa naa ni nnkan bii aago mejo koja iseju marundinlogun. Baba omo yii, Hakeem Mustapha, lo mu esun to ajo naa wa pe Ishola ti fipa ba omo oun obinrin ti ko ju omo odun mesan-an lo lo po.Esun ti Hakeem mu to won lo lo fa a ti won fi bere si i sewadii, ko si pe ti won fi nawo gan Ishola, eni to ni adugbo Monatan, n'Ibadan, loun n gbe. Gege bi iwadii ajo Sifu Difensi se safihan re, se ni omokunrin yii ati enikan ti won pe oruko re ni Ojoluyi Tomisin, eni to ti na papa bora bayii jo gbimo-po lati fipa ba omodebinrin naa lo po, leyin eyi ni won tun fi ankasiifu funfun nu eje to jade loju ara e, ti won si mu un lo sibi ti enikan ko mo.

Iwadii Iwe Irohin Yoruba fihan pe akekoo ipele to gbeyin ni ile eko Lautech, l'Ogbomoso, ni Ishola, to si je pe lasiko to huwa laabi yii lo n ko ise asepari re (project) lowo. Ni bayii, won si n wa Tomisin.

Sa, Henry Bilesanmi ti fidi isele yii mule fun akoroyin wa, o ni awon ti taari ejo naa sile-ejo, nibi ti Ishola yoo ti maa so tenu e. Akoroyin wa ri gbo pe kootu majisreeti kan nipinle Kwara, eyi ti Adajo F.O Olokoyo wa ni won wo Ishola lo, ti adajo naa si ti pase pe ki won fi i pamo si ogba ewon Oke-kura, n'Ilorin.


 Posted By Ifiranse Eleyi Je Wednesday, October 14 @ 16:45:21 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 

Comments 💬 التعليقات
 

For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا

Awọn ọna asopọ ti o jọmọ

· Die sii Nipa Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga
· Iroyin Nipasẹ MediaYorubaTeam


Ọpọlọpọ Itan Ka Nipa Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga:
O Sele! Iya Nimota Lo Oogun Ti Oyan E Fi Maa Tobi Si i, Loko Ba Da Eru E Sita: B


Iwọn Abala

Apapọ Dimegilio: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

Jọ̀wọ́ Gba Ẹ̀ẹ̀kejI ki o sI dIbo fun Abala YIi:

O tayọ
O dara pupọ
O dara
Deede
Buburu


Aṣayan


 Ọrẹ-itẹwe Ọrẹ-itẹweAkole Atoka Agbo-Oro

Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga

"Ishola Fipa Ba Omo Odun Mesan-an Lo Po N'Ilorin, O Tun Fi Ankasiifu Nu Oju " | Buwolu wọle/Ṣẹda Eto Akọsilẹ | 0 Awon Alaiye


Awọn asọye jẹ Ohun ini nipasẹ Iwe ifiweranṣẹ. A Ko Lodidi Fun Akoonu wọn. Nibayi, A Pe Awọn oluka lati jabo Eyikeyi Abusive, Unsuitable And/tabi Islamophobic Content

Ko si awọn ọrọIwoye Ti o gba laaye Fun Aisinisi, Jọwọ Forukọsilẹ
 

EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And IslamAfrica.Com