Gbagede Yoruba
 
Sunday ki iyawo ore re mole n'Ilorin, lo ba fipa ba a lo po
 
Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga Lati Owo Stephen Ajagbe, Ilorin

Sunday ki iyawo ore re mole n'Ilorin, lo ba fipa ba a lo po

Odomokunrin eni odun metalelogun kan, Sunday Akano, ti wo gau bayii nitori esun ti won fi kan an pe o ki iyawo ore re mole, ile-ejo si ti pase ko si wa lahaamo ogba ewon.

Afurasi ohun lo fogbon tan omobinrin to je iyawo ore re yii wa sinu ile re, nibi to ti ki i mole ni tipa, to si se e basubasu. Agbegbe Adewole, niluu Ilorin, nisele ohun ti waye ko too di pe ileese olopaa 'D Division' to wa ni Adewole gbe ejo omokunrin ohun wa si eka to n sewadii iwa odaran ni olu ileese olopaa nipinle Kwara leyin towo te e.

Lati Owo Stephen Ajagbe, Ilorin

 Posted By Ifiranse Eleyi Je Thursday, June 18 @ 06:48:06 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
Comments 💬 التعليقات
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا

Awọn ọna asopọ ti o jọmọ

· Die sii Nipa Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga
· Iroyin Nipasẹ MediaYorubaTeam

Ọpọlọpọ Itan Ka Nipa Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga:
O Sele! Iya Nimota Lo Oogun Ti Oyan E Fi Maa Tobi Si i, Loko Ba Da Eru E Sita: B

Iwọn Abala

Apapọ Dimegilio: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

Jọ̀wọ́ Gba Ẹ̀ẹ̀kejI ki o sI dIbo fun Abala YIi:

O tayọ
O dara pupọ
O dara
Deede
Buburu

Aṣayan

 Ọrẹ-itẹwe Ọrẹ-itẹweAkole Atoka Agbo-Oro

Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga

"Sunday ki iyawo ore re mole n'Ilorin, lo ba fipa ba a lo po" | Buwolu wọle/Ṣẹda Eto Akọsilẹ | 0 Awon Alaiye

Awọn asọye jẹ Ohun ini nipasẹ Iwe ifiweranṣẹ. A Ko Lodidi Fun Akoonu wọn. Nibayi, A Pe Awọn oluka lati jabo Eyikeyi Abusive, Unsuitable And/tabi Islamophobic Content

Ko si awọn ọrọIwoye Ti o gba laaye Fun Aisinisi, Jọwọ Forukọsilẹ
 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And IslamAfrica.Com