Gbagede Yoruba
 

 
Odetola lu magun lara iyawo e n'Ilesa, eemeta lo gbokiti
 
Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga
Lati Owo Bisi Adesoye, Ilesa

Odetola lu magun lara iyawo e n'Ilesa, eemeta lo gbokiti

Ogbeni Odetola, eni ogorin odun to je oluko-feyinti ti kagbako iku ojiji pelu bo se lu magun lori iyawo re, Arabinrin Arike l'Ojoru, Tosde, ose to koja.

Oloogbe Odetola feyinti ninu ise oluko lodun to koja, bee l'Iwe Iroyin Yoruba gbo pe okunrin naa ni afojusun pe o maa ko lo sinu ile to n ko lodun to pari yii.

Odetola la gbo pe o bi omo merin, iyen Folake, Dupe, Alaba ati Oyekunle. Folake to je akobi wa nileewe fasiti kan ni orile-ede yii, awon to ku si wa ni ileewe girama ati ileewe alakoobere nipinle Osun.Iwe Iroyin Yoruba gbo pe bi Odetola se wole ni ojo buruku esu gbomi-mu naa ni iyawo re to ko lati kopa ninu eto adura toko re loo se nileejosin bere ere ife pelu e, tiyen si ba a lasepo. Leyin iseju meji si merin tawon mejeeji wole ni eko ko soju mimu fun okunrin yii pelu bo se pariwo pe, ''N ko ni i ta eeketa, n ko ni i ta eeketa'', eyi tokan ninu awon omo re gbo, to si figbe ta. Sugbon ki iranlowo too de sodo won ni baale ile naa ti takiti keta, to si se bee gbemii mi.

Nigba ti Iwe Iroyin Yoruba n ba araadugbo kan, Arakunrin Adeolu to je ore oloogbe soro, o salaye pe oun ti sekilo fun Odetola lori agbere tiyawo re gunle, sugbon ti ko kobi ara si i.

O ni bii igba merin loun ti ri Arike pelu awon oloselu, to je pe won gbe e lo sileetura lati ba a lasepo.

Gbogbo akitiyan akoroyin wa lati ba Arike soro lo ja si pabo nitori to ti sa lo sodo awon obi re ni Ile-Ife, nipinle Osun. Bee ni akobi oloogbe naa ko lati ba wa soro.

Lasiko ti a n ko iroyin yii jo, oku Odetola ti wa ni mosuari ileewosan Wesley.


 Posted By Ifiranse Eleyi Je Tuesday, April 28 @ 01:14:26 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 

Comments 💬 التعليقات
 

For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا

Awọn ọna asopọ ti o jọmọ

· Die sii Nipa Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga
· Iroyin Nipasẹ MediaYorubaTeam


Ọpọlọpọ Itan Ka Nipa Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga:
O Sele! Iya Nimota Lo Oogun Ti Oyan E Fi Maa Tobi Si i, Loko Ba Da Eru E Sita: B


Iwọn Abala

Apapọ Dimegilio: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

Jọ̀wọ́ Gba Ẹ̀ẹ̀kejI ki o sI dIbo fun Abala YIi:

O tayọ
O dara pupọ
O dara
Deede
Buburu


Aṣayan


 Ọrẹ-itẹwe Ọrẹ-itẹweAkole Atoka Agbo-Oro

Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga

"Odetola lu magun lara iyawo e n'Ilesa, eemeta lo gbokiti" | Buwolu wọle/Ṣẹda Eto Akọsilẹ | 0 Awon Alaiye


Awọn asọye jẹ Ohun ini nipasẹ Iwe ifiweranṣẹ. A Ko Lodidi Fun Akoonu wọn. Nibayi, A Pe Awọn oluka lati jabo Eyikeyi Abusive, Unsuitable And/tabi Islamophobic Content

Ko si awọn ọrọIwoye Ti o gba laaye Fun Aisinisi, Jọwọ Forukọsilẹ
 

EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And IslamAfrica.Com